Javascript must be enabled to continue!
Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
View through CrossRef
Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile. Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo. Eredie ree ti a wa fi lo tiori imo abinibi lati wo bi awon Yoruba se n samulo awon nnkan ti o wa larowoto ati ayika won. Agbalo agbabo ni pe a ri eri pe opo imo ibile lo je yo ti o si hande ninu oriki orile, paapaa awon eyi ti ijoba ile Naijiria i ba fi pese ise fun ogoro odo ti won fese gba igboro kiri. Lara imo abinibi ti a ri naa ni ise ona sise, ile kiko lona ibile, aso hibun ati ise tewe-tegbo.
University of Florida George A Smathers Libraries
Title: Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
Description:
Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile.
Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo.
Eredie ree ti a wa fi lo tiori imo abinibi lati wo bi awon Yoruba se n samulo awon nnkan ti o wa larowoto ati ayika won.
Agbalo agbabo ni pe a ri eri pe opo imo ibile lo je yo ti o si hande ninu oriki orile, paapaa awon eyi ti ijoba ile Naijiria i ba fi pese ise fun ogoro odo ti won fese gba igboro kiri.
Lara imo abinibi ti a ri naa ni ise ona sise, ile kiko lona ibile, aso hibun ati ise tewe-tegbo.
.
Related Results
A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language
A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language
OF: Èdè Yorùbá ni á ̀kóko yìí tí ̀ ń lọ sí òkun ìgbàgbé, níbo ni ọr̀ ọ yìí tí w ̀ ọ wá?
TF: Hmm, ìbéèrè tó ṣe kókó tó ṣe pàtàkì tó ń kọni lóminú rèé. Lotitọ, èdè abínibí w...
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Ọ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí ...
Osvrt na nalaze karolinške provenijencije u Ninu povodom novog nalaza karolinškog jezičca
Osvrt na nalaze karolinške provenijencije u Ninu povodom novog nalaza karolinškog jezičca
U ovom radu željeli smo pokazati važnost Nina kao jednog od prvih kultumo-političkih i vjerskih centara ranofeudalne Hrvatske kneževine, kroz prizmu materijalne i duhovne ostavštin...
Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá
Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá
Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoruba, papaa julo nipa lilo awon ere idaraya keekeeke lori ero konputa fun kiko ede...
Nama : Angel Evangelist Foni Sopo Ninu (130118109)
Nama : Angel Evangelist Foni Sopo Ninu (130118109)
Dalam era globalisasi,timbul persaingan yang meningkat pesat sehingga dibutuhkan kinerja yang dapat membuat perusahaan mampu bersaing. Firm Performance merupakan kemampuan dan stra...
Clinical spectrum and outcomes of cancer patients affected with COVID-19 in Indian population: A single-center retrospective study
Clinical spectrum and outcomes of cancer patients affected with COVID-19 in Indian population: A single-center retrospective study
Introduction: Cancer patients affected with COVID-19 are at high risk of severe infection and death which depends upon their functional status, cancer type and treatment modality. ...
Evaluation of body mass index and lipid profiles among Joseph Ayo Babalola University students, Ikeji Arakeji, Osun state, Nigeria
Evaluation of body mass index and lipid profiles among Joseph Ayo Babalola University students, Ikeji Arakeji, Osun state, Nigeria
The aim of the study was to access the relationship between body mass index and lipid profiles among Joseph Ayo Babalola University Students as a means of evaluating their cardiova...
Entrepreneurship attainment through the AFE Babalola university programme
Entrepreneurship attainment through the AFE Babalola university programme
Entrepreneurship education plays a pivotal role in fostering economic
development, reducing poverty, and generating employment opportunities,
particularly in emerging economies lik...

