Javascript must be enabled to continue!
Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá
View through CrossRef
Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoruba, papaa julo nipa lilo awon ere idaraya keekeeke lori ero konputa fun kiko ede Yoruba. Ninu apileko naa, a safihan awon ere onimo ero gbajugbaja ti oluko le samulo won fun kiko ede Yoruba gege bii Jeopardy (Jeopaadi), Who Wants to be a Millionaire (Ta lo fe dololoa?), ati Wordsearch (Isawari Oro). Nipari, apileko naa se alaye to kun nipa arifani ati isoro ti o so mo awon ere ori ero wonyi.
Title: Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá
Description:
Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoruba, papaa julo nipa lilo awon ere idaraya keekeeke lori ero konputa fun kiko ede Yoruba.
Ninu apileko naa, a safihan awon ere onimo ero gbajugbaja ti oluko le samulo won fun kiko ede Yoruba gege bii Jeopardy (Jeopaadi), Who Wants to be a Millionaire (Ta lo fe dololoa?), ati Wordsearch (Isawari Oro).
Nipari, apileko naa se alaye to kun nipa arifani ati isoro ti o so mo awon ere ori ero wonyi.
.
Related Results
Yoruba Mythology in Wole Soyinka’s A Dance of the Forests and The Road
Yoruba Mythology in Wole Soyinka’s A Dance of the Forests and The Road
Cette étude porte sur les catégories et les fonctions de la mythologie Yoruba dans deux des pièces de théâtre de Wole Soyinka à savoir A Dance of the Forests et The Road. Les types...
A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language
A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language
OF: Èdè Yorùbá ni á ̀kóko yìí tí ̀ ń lọ sí òkun ìgbàgbé, níbo ni ọr̀ ọ yìí tí w ̀ ọ wá?
TF: Hmm, ìbéèrè tó ṣe kókó tó ṣe pàtàkì tó ń kọni lóminú rèé. Lotitọ, èdè abínibí w...
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Ọ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí ...
VIETNAMESE - EDE BILINGUAL EDUCATION IN PRIMARY SCHOOLS IN DAK LAK PROVINCE, VIETNAM
VIETNAMESE - EDE BILINGUAL EDUCATION IN PRIMARY SCHOOLS IN DAK LAK PROVINCE, VIETNAM
In Dak Lak, the Ede has the second largest population (after the Kinh). In the process of communication, the Ede language has a language contact relationship with Vietnamese. There...
A Sociolinguistic Analysis of Gender Differentiation in Yoruba Burial Rites
A Sociolinguistic Analysis of Gender Differentiation in Yoruba Burial Rites
This paper focuses on socio-hermeneutic study of gender differentiation in Yoruba burial rites. There are many types of oral genres in Yoruba society. These genres have different f...
MIMOS 2024
MIMOS 2024
Lilo Baurs Theater lebt von der starken körperlichen Unmittelbarkeit. Seelenregungen gerinnen bei ihr zu vielsagenden Haltungen und Gesten, in denen sie oft auch eine entlarvende K...
Identification of neurocorrelates of loss of control eating
Identification of neurocorrelates of loss of control eating
Introduction: Loss of Control (LOC) eating leads to positive energy balance and higher instances of chronic diseases, and is, regardless of the amount consumed, defined as a subjec...
The Art and life of Alàgbà Fálétí – A Pic torial, Art and Artifacts Exhibition in Honor of Alàgbà Adébáyọ̀ Fálétí (1921- 2017) curated by Akinsola Adejuwon and Seyi Ogunjobi
The Art and life of Alàgbà Fálétí – A Pic torial, Art and Artifacts Exhibition in Honor of Alàgbà Adébáyọ̀ Fálétí (1921- 2017) curated by Akinsola Adejuwon and Seyi Ogunjobi
Alàgbà Adébáyọ Fálétí to generations both in “town and gown” is a Yorùbá ̀ iconic cultural statement. His life was a window to different historical epochs in Nigeria. A life that s...

