Search engine for discovering works of Art, research articles, and books related to Art and Culture
ShareThis
Javascript must be enabled to continue!

Àkànlò-èdè Tuntun Nínú Àwọn Orin Ọ ̀ dọ ́ Ìwòyí

View through CrossRef
Àkaǹlò èdè Yorùbá tuntun je ̣ ́ ìpèdè tí Àkànmú (2016) pè ní ìsọ ìgbàlódé tí ìtumò wọn loorìn díè tí ó sì ṣàjèjì sí àwọn tí ó máa ń ṣe àmúlò àkànlò èdè ti ̣ - wa-n-tiwa tí ó ti wà te ̣ ́ lè . Ọ̣ ̀pòḷọpo ̣ ̀ ̀ iṣe ̣ ̣ ́ ìwádìí ní ó ti wà lórí ìṣàmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin, fíìmù àgbéléwò, ìpolówó ọjà, ìròyìn, o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ nínú eré boòlù àfẹse ̣ ̣ ̀ gbá láàrin àwọn èrò ìwòran ní gbàgede ìwòran àti ìgbòkègbodò ọko ̣ ̀ ṣùgbó n kò fi bee ̣ ̀ sí iṣé tí ó jinle ̣ ̣ ̀ lórí ìjẹyọ àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin tàka-súfèé òde òní èyí tó wo ̣ ́ po ̣ ̀ láàrin àwọn o ̣ ̀ do ̣ ́ . Akitiyan láti dí àlàfo yìí ní ó bí àpile ̣ ̀ kọ yìí. Tío ̣ ́ rì èdè ojoojúmó (̣ Standard Language Theory) tí Mukarovsky ṣe agbáterù re ̣ ̀ ni a fi ṣe àtúpalè àwọn àkànlò èdè Yorùbá ̣ tuntun tí á yè wò nínú bébà yìí nítorí pé ó lè ṣàlàyé ohun tí ó je ̣ ̣ ́ kí àkànlò èdè Yorùbá tuntun yapa si èdè ojoojúmo ̣ ́ àti ohun tí ó ń fa ìyàtò gír ̣ íkì láàrin èdè ojoojúmó àti èdè ewì. A ṣe àṣàyàn o ̣ ̣ ̀ kọrin tàka-súfèé me ̣ ́ ta wonyi: Olátúnjí Ọládo ̣ ̀ tun À ̀làdé (Dotman), Azeez Fáṣọlá (Naira Marley) àti Oritse Fe ̣ ́ mi Má- je ̣ ̀ e ̣ ́ mite ̣ ́ Èkélè (Oritsa Fémi) nítorí pé àkànlò èdè Yorùbá tuntun farahàn púpo ̣ ̀ nínú orin wọn. Nínú ìtúpalè wa ni ó ti hàn pé àwọn o ̣ ̣ ̀ kọrin tàka-súfèé òde-òní fe ̣ ́ ràn láti máa ṣe àmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun bí i ‘oúnjẹ ọmọ’ (fún obìnrin tí ó ní ọyàn ńlá èyí tí ó bù kún ẹwà a rè ), ‘je ̣ ̣ ̀ wà’ (s ̣ ̀ ewo ̣ ̀ n), ‘ojúẹle ̣ ́ gba’ (oluko, ará oko èèyàn tàbí ẹni tí ojú re ̣ ̀ dúdú), ‘gbé bo ̣ ́ dì ẹ’ (lo ọpọlọ tàbí ọgbo ̣ ́ n orí ẹ) àti ‘yàúyàhúù’ (àwọn tí ó ń fi e ̣ ̀ rọ ayélujára lu jìbìtì) ge ̣ ́ ge ̣ ́ bí o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ àti ìdánilárayá. A ṣe àmúlò àfiwé ẹle ̣ ́ lo ̣ ̀ o ̣ ́ fún ìṣe ̣ ̀ dá àwọn àkànlò èdè Yorùbá tuntun tí ó jẹ yọ. Àfiwé ẹle ̣ ́ lò ọ ̣ ́ yìí náà ni ó bí ìsọdorúkọ, fìrósínròójẹ àti àwọn èròjà ìṣe ̣ ̀ dá o ̣ ̀ ro ̣ ̀ mìíràn tí a lò nínú àpile ̣ ̀ kọ yìí. Ó hàn gbangba pé àkànlò èdè Yorùbá tuntun rẹwà jù lọ fún ìbáraẹniso ̣ ̀ ro ̣ ̀ , ṣíṣe àlàyé o ̣ ̀ ro ̣ ̀ , àpèjúwe àti ìdárayá nínú orin tàka-súfèé
University of Florida George A Smathers Libraries
Title: Àkànlò-èdè Tuntun Nínú Àwọn Orin Ọ ̀ dọ ́ Ìwòyí
Description:
Àkaǹlò èdè Yorùbá tuntun je ̣ ́ ìpèdè tí Àkànmú (2016) pè ní ìsọ ìgbàlódé tí ìtumò wọn loorìn díè tí ó sì ṣàjèjì sí àwọn tí ó máa ń ṣe àmúlò àkànlò èdè ti ̣ - wa-n-tiwa tí ó ti wà te ̣ ́ lè .
Ọ̣ ̀pòḷọpo ̣ ̀ ̀ iṣe ̣ ̣ ́ ìwádìí ní ó ti wà lórí ìṣàmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin, fíìmù àgbéléwò, ìpolówó ọjà, ìròyìn, o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ nínú eré boòlù àfẹse ̣ ̣ ̀ gbá láàrin àwọn èrò ìwòran ní gbàgede ìwòran àti ìgbòkègbodò ọko ̣ ̀ ṣùgbó n kò fi bee ̣ ̀ sí iṣé tí ó jinle ̣ ̣ ̀ lórí ìjẹyọ àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin tàka-súfèé òde òní èyí tó wo ̣ ́ po ̣ ̀ láàrin àwọn o ̣ ̀ do ̣ ́ .
Akitiyan láti dí àlàfo yìí ní ó bí àpile ̣ ̀ kọ yìí.
Tío ̣ ́ rì èdè ojoojúmó (̣ Standard Language Theory) tí Mukarovsky ṣe agbáterù re ̣ ̀ ni a fi ṣe àtúpalè àwọn àkànlò èdè Yorùbá ̣ tuntun tí á yè wò nínú bébà yìí nítorí pé ó lè ṣàlàyé ohun tí ó je ̣ ̣ ́ kí àkànlò èdè Yorùbá tuntun yapa si èdè ojoojúmo ̣ ́ àti ohun tí ó ń fa ìyàtò gír ̣ íkì láàrin èdè ojoojúmó àti èdè ewì.
A ṣe àṣàyàn o ̣ ̣ ̀ kọrin tàka-súfèé me ̣ ́ ta wonyi: Olátúnjí Ọládo ̣ ̀ tun À ̀làdé (Dotman), Azeez Fáṣọlá (Naira Marley) àti Oritse Fe ̣ ́ mi Má- je ̣ ̀ e ̣ ́ mite ̣ ́ Èkélè (Oritsa Fémi) nítorí pé àkànlò èdè Yorùbá tuntun farahàn púpo ̣ ̀ nínú orin wọn.
Nínú ìtúpalè wa ni ó ti hàn pé àwọn o ̣ ̣ ̀ kọrin tàka-súfèé òde-òní fe ̣ ́ ràn láti máa ṣe àmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun bí i ‘oúnjẹ ọmọ’ (fún obìnrin tí ó ní ọyàn ńlá èyí tí ó bù kún ẹwà a rè ), ‘je ̣ ̣ ̀ wà’ (s ̣ ̀ ewo ̣ ̀ n), ‘ojúẹle ̣ ́ gba’ (oluko, ará oko èèyàn tàbí ẹni tí ojú re ̣ ̀ dúdú), ‘gbé bo ̣ ́ dì ẹ’ (lo ọpọlọ tàbí ọgbo ̣ ́ n orí ẹ) àti ‘yàúyàhúù’ (àwọn tí ó ń fi e ̣ ̀ rọ ayélujára lu jìbìtì) ge ̣ ́ ge ̣ ́ bí o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ àti ìdánilárayá.
A ṣe àmúlò àfiwé ẹle ̣ ́ lo ̣ ̀ o ̣ ́ fún ìṣe ̣ ̀ dá àwọn àkànlò èdè Yorùbá tuntun tí ó jẹ yọ.
Àfiwé ẹle ̣ ́ lò ọ ̣ ́ yìí náà ni ó bí ìsọdorúkọ, fìrósínròójẹ àti àwọn èròjà ìṣe ̣ ̀ dá o ̣ ̀ ro ̣ ̀ mìíràn tí a lò nínú àpile ̣ ̀ kọ yìí.
Ó hàn gbangba pé àkànlò èdè Yorùbá tuntun rẹwà jù lọ fún ìbáraẹniso ̣ ̀ ro ̣ ̀ , ṣíṣe àlàyé o ̣ ̀ ro ̣ ̀ , àpèjúwe àti ìdárayá nínú orin tàka-súfèé.

Related Results

Ìtúpalẹ ̀ Àṣàyàn Oríkì Ẹranko
Ìtúpalẹ ̀ Àṣàyàn Oríkì Ẹranko
Àwọn Yorùbá fé ràn oríkì púpo ̣ ̀ , wo ̣ ́ n sì gbádùn láti máa lò ó nígbà gbogbo ̣ tí ohun tí ó jẹ mó ọn bá wáyé. Ní ilé ayé, oríṣiríṣi ni iṣe ̣...
A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language
A Conversation with Toyin Falola on the future of Yoruba Language
OF: Èdè Yorùbá ni á ̀kóko yìí tí ̀ ń lọ sí òkun ìgbàgbé, níbo ni ọr̀ ọ yìí tí w ̀ ọ wá? TF: Hmm, ìbéèrè tó ṣe kókó tó ṣe pàtàkì tó ń kọni lóminú rèé. Lotitọ, èdè abínibí w...
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Ọ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí ...
A Semiotic Analysis of Orin Ọ̀tẹ̀: Yorùbá Performance Art in Song-Lashing
A Semiotic Analysis of Orin Ọ̀tẹ̀: Yorùbá Performance Art in Song-Lashing
Fela Kuti pronounced music a weapon, but nowhere in the Nigerian space is the weaponization of music more prominent than in the political space. This study identifies and examines ...
Forecasting Young Apple Tree Bud Status with a Visible/Near-Infrared Spectrometer
Forecasting Young Apple Tree Bud Status with a Visible/Near-Infrared Spectrometer
Being able to ascertain the physiological condition of the buds on a young apple tree before bud burst could help farmers manage their orchards more efficiently, especially if they...
Magnetic and Restivity Investigation of Geologic Structures in the Basement Complex of Aran-orin, Kwara-state, Nigeria.
Magnetic and Restivity Investigation of Geologic Structures in the Basement Complex of Aran-orin, Kwara-state, Nigeria.
Abstract This study aims at integration of magnetic and vertical electrical sounding (VES) resistivity methods to determine groundwater prospective in part of Aran-orin She...

Back to Top